Quran with Yoruba translation - Surah Ghafir ayat 76 - غَافِر - Page - Juz 24
﴿ٱدۡخُلُوٓاْ أَبۡوَٰبَ جَهَنَّمَ خَٰلِدِينَ فِيهَاۖ فَبِئۡسَ مَثۡوَى ٱلۡمُتَكَبِّرِينَ ﴾
[غَافِر: 76]
﴿ادخلوا أبواب جهنم خالدين فيها فبئس مثوى المتكبرين﴾ [غَافِر: 76]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ẹ wọ àwọn ẹnu ọ̀na iná Jahanamọ; olùṣegbére ni wọ́n nínú rẹ̀. Ó sì burú ní ibùgbé fún àwọn onígbèéraga |