Quran with Yoruba translation - Surah Ghafir ayat 81 - غَافِر - Page - Juz 24
﴿وَيُرِيكُمۡ ءَايَٰتِهِۦ فَأَيَّ ءَايَٰتِ ٱللَّهِ تُنكِرُونَ ﴾
[غَافِر: 81]
﴿ويريكم آياته فأي آيات الله تنكرون﴾ [غَافِر: 81]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni (Allāhu) ń fi àwọn àmì Rẹ̀ hàn yín. Nítorí náà, èwo nínú àwọn àmì Allāhu l’ẹ máa takò |