Quran with Yoruba translation - Surah Al-Jathiyah ayat 3 - الجاثِية - Page - Juz 25
﴿إِنَّ فِي ٱلسَّمَٰوَٰتِ وَٱلۡأَرۡضِ لَأٓيَٰتٖ لِّلۡمُؤۡمِنِينَ ﴾
[الجاثِية: 3]
﴿إن في السموات والأرض لآيات للمؤمنين﴾ [الجاثِية: 3]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Dájúdájú nínú àwọn sánmọ̀ àti ilẹ̀ àwọn àmì wà (nínú wọn) fún àwọn onígbàgbọ́ òdodo |