Quran with Yoruba translation - Surah Al-Jathiyah ayat 4 - الجاثِية - Page - Juz 25
﴿وَفِي خَلۡقِكُمۡ وَمَا يَبُثُّ مِن دَآبَّةٍ ءَايَٰتٞ لِّقَوۡمٖ يُوقِنُونَ ﴾
[الجاثِية: 4]
﴿وفي خلقكم وما يبث من دابة آيات لقوم يوقنون﴾ [الجاثِية: 4]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Àwọn àmì wà nínú ìṣẹ̀dá yín àti ohun tí Allāhu ń fọ́nká (sórí ilẹ̀) nínú àwọn n̄ǹkan abẹ̀mí; (àmì wà nínú wọn) fún ìjọ t’ó ní àmọ̀dájú |