Quran with Yoruba translation - Surah Qaf ayat 10 - قٓ - Page - Juz 26
﴿وَٱلنَّخۡلَ بَاسِقَٰتٖ لَّهَا طَلۡعٞ نَّضِيدٞ ﴾
[قٓ: 10]
﴿والنخل باسقات لها طلع نضيد﴾ [قٓ: 10]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni (A tún mú) igi dàbínù hù ga, tí àwọn èso orí rẹ̀ so jìgbìnnì |