Quran with Yoruba translation - Surah Adh-Dhariyat ayat 36 - الذَّاريَات - Page - Juz 27
﴿فَمَا وَجَدۡنَا فِيهَا غَيۡرَ بَيۡتٖ مِّنَ ٱلۡمُسۡلِمِينَ ﴾
[الذَّاريَات: 36]
﴿فما وجدنا فيها غير بيت من المسلمين﴾ [الذَّاريَات: 36]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni A ò sì rí nínú (ìlú náà) tayọ ilé kan t’ó jẹ́ ti àwọn mùsùlùmí |