Quran with Yoruba translation - Surah Adh-Dhariyat ayat 37 - الذَّاريَات - Page - Juz 27
﴿وَتَرَكۡنَا فِيهَآ ءَايَةٗ لِّلَّذِينَ يَخَافُونَ ٱلۡعَذَابَ ٱلۡأَلِيمَ ﴾
[الذَّاريَات: 37]
﴿وتركنا فيها آية للذين يخافون العذاب الأليم﴾ [الذَّاريَات: 37]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni A sì fi àmì kan sílẹ̀ nínú (ìlú náà) fún àwọn t’ó ń páyà ìyà ẹlẹ́ta-eléro |