Quran with Yoruba translation - Surah AT-Tur ayat 25 - الطُّور - Page - Juz 27
﴿وَأَقۡبَلَ بَعۡضُهُمۡ عَلَىٰ بَعۡضٖ يَتَسَآءَلُونَ ﴾
[الطُّور: 25]
﴿وأقبل بعضهم على بعض يتساءلون﴾ [الطُّور: 25]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Apá kan wọn yóò dojú kọ apá kan, wọn yó sì máa bèèrè ọ̀rọ̀ lọ́wọ́ ara wọn |