Quran with Yoruba translation - Surah An-Najm ayat 8 - النَّجم - Page - Juz 27
﴿ثُمَّ دَنَا فَتَدَلَّىٰ ﴾
[النَّجم: 8]
﴿ثم دنا فتدلى﴾ [النَّجم: 8]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Lẹ́yìn náà, ó sún mọ́ (Ànábì). Ó sì sọ̀kalẹ̀ (tọ̀ ọ́ wá) |