Quran with Yoruba translation - Surah Al-Waqi‘ah ayat 3 - الوَاقِعة - Page - Juz 27
﴿خَافِضَةٞ رَّافِعَةٌ ﴾
[الوَاقِعة: 3]
﴿خافضة رافعة﴾ [الوَاقِعة: 3]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni ó máa mú (àwọn kan) wálẹ̀ (sínú Iná), ó sì máa gbé (àwọn kan) sókè (nínú Ọgbà Ìdẹ̀ra) |