Quran with Yoruba translation - Surah Al-Mujadilah ayat 20 - المُجَادلة - Page - Juz 28
﴿إِنَّ ٱلَّذِينَ يُحَآدُّونَ ٱللَّهَ وَرَسُولَهُۥٓ أُوْلَٰٓئِكَ فِي ٱلۡأَذَلِّينَ ﴾
[المُجَادلة: 20]
﴿إن الذين يحادون الله ورسوله أولئك في الأذلين﴾ [المُجَادلة: 20]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Dájúdájú àwọn t’ó ń yapa Allāhu àti Òjíṣẹ́ Rẹ̀, àwọn wọ̀nyẹn wà nínú àwọn olùyẹpẹrẹ jùlọ |