Quran with Yoruba translation - Surah Al-An‘am ayat 117 - الأنعَام - Page - Juz 8
﴿إِنَّ رَبَّكَ هُوَ أَعۡلَمُ مَن يَضِلُّ عَن سَبِيلِهِۦۖ وَهُوَ أَعۡلَمُ بِٱلۡمُهۡتَدِينَ ﴾
[الأنعَام: 117]
﴿إن ربك هو أعلم من يضل عن سبيله وهو أعلم بالمهتدين﴾ [الأنعَام: 117]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Dájúdájú Olúwa rẹ, Òun l’Ó nímọ̀ jùlọ nípa ẹni t’ó ṣìnà lójú ọ̀nà (ẹ̀sìn) Rẹ̀. Àti pé, Òun sì l’Ó nímọ̀ jùlọ nípa àwọn olùmọ̀nà |