×

(Allahu da eran) mejo ni tako-tabo; meji ninu agutan (tako-tabo), meji ninu 6:143 Yoruba translation

Quran infoYorubaSurah Al-An‘am ⮕ (6:143) ayat 143 in Yoruba

6:143 Surah Al-An‘am ayat 143 in Yoruba (اليوربا)

Quran with Yoruba translation - Surah Al-An‘am ayat 143 - الأنعَام - Page - Juz 8

﴿ثَمَٰنِيَةَ أَزۡوَٰجٖۖ مِّنَ ٱلضَّأۡنِ ٱثۡنَيۡنِ وَمِنَ ٱلۡمَعۡزِ ٱثۡنَيۡنِۗ قُلۡ ءَآلذَّكَرَيۡنِ حَرَّمَ أَمِ ٱلۡأُنثَيَيۡنِ أَمَّا ٱشۡتَمَلَتۡ عَلَيۡهِ أَرۡحَامُ ٱلۡأُنثَيَيۡنِۖ نَبِّـُٔونِي بِعِلۡمٍ إِن كُنتُمۡ صَٰدِقِينَ ﴾
[الأنعَام: 143]

(Allahu da eran) mejo ni tako-tabo; meji ninu agutan (tako-tabo), meji ninu ewure (tako-tabo). So pe: "Se awon ako mejeeji ni Allahu se ni eewo ni tabi abo mejeeji, tabi ohun ti n be ninu apo-ibimo awon abo eran mejeeji. E fun mi ni iro pelu imo ti e ba je olododo

❮ Previous Next ❯

ترجمة: ثمانية أزواج من الضأن اثنين ومن المعز اثنين قل آلذكرين حرم أم, باللغة اليوربا

﴿ثمانية أزواج من الضأن اثنين ومن المعز اثنين قل آلذكرين حرم أم﴾ [الأنعَام: 143]

Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
(Allāhu dá ẹran) mẹ́jọ ní takọ-tabo; méjì nínú àgùtàn (takọ-tabo), méjì nínú ewúrẹ́ (takọ-tabo). Sọ pé: "Ṣé àwọn akọ méjèèjì ni Allāhu ṣe ní èèwọ̀ ni tàbí abo méjèèjì, tàbí ohun tí ń bẹ nínú àpò-ìbímọ àwọn abo ẹran méjèèjì. Ẹ fún mi ní ìró pẹ̀lú ìmọ̀ tí ẹ bá jẹ́ olódodo
❮ Previous Next ❯

Verse in more languages

Transliteration Bangla Bosnian German English Persian French Hindi Indonesian Kazakh Dutch Russian Spanish Turkish Urdu Uzbek