Quran with Yoruba translation - Surah Al-Mulk ayat 25 - المُلك - Page - Juz 29
﴿وَيَقُولُونَ مَتَىٰ هَٰذَا ٱلۡوَعۡدُ إِن كُنتُمۡ صَٰدِقِينَ ﴾
[المُلك: 25]
﴿ويقولون متى هذا الوعد إن كنتم صادقين﴾ [المُلك: 25]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Wọ́n ń wí pé: "Ìgbà wo ni àdéhùn yìí yóò ṣẹ tí ẹ bá jẹ́ olódodo |