Quran with Yoruba translation - Surah Al-Mulk ayat 24 - المُلك - Page - Juz 29
﴿قُلۡ هُوَ ٱلَّذِي ذَرَأَكُمۡ فِي ٱلۡأَرۡضِ وَإِلَيۡهِ تُحۡشَرُونَ ﴾
[المُلك: 24]
﴿قل هو الذي ذرأكم في الأرض وإليه تحشرون﴾ [المُلك: 24]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Sọ pé: "Òun ni Ẹni tí Ó da yín sí orí ilẹ̀. Ọ̀dọ̀ Rẹ̀ sì ni wọn yóò ko yín jọ sí |