Quran with Yoruba translation - Surah Al-Mulk ayat 26 - المُلك - Page - Juz 29
﴿قُلۡ إِنَّمَا ٱلۡعِلۡمُ عِندَ ٱللَّهِ وَإِنَّمَآ أَنَا۠ نَذِيرٞ مُّبِينٞ ﴾
[المُلك: 26]
﴿قل إنما العلم عند الله وإنما أنا نذير مبين﴾ [المُلك: 26]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Sọ pé: "Ọ̀dọ̀ Allāhu nìkan ni ìmọ̀ (nípa) rẹ̀ wà. Èmi kàn jẹ́ olùkìlọ̀ pọ́nńbélé ni |