Quran with Yoruba translation - Surah Al-A‘raf ayat 67 - الأعرَاف - Page - Juz 8
﴿قَالَ يَٰقَوۡمِ لَيۡسَ بِي سَفَاهَةٞ وَلَٰكِنِّي رَسُولٞ مِّن رَّبِّ ٱلۡعَٰلَمِينَ ﴾
[الأعرَاف: 67]
﴿قال ياقوم ليس بي سفاهة ولكني رسول من رب العالمين﴾ [الأعرَاف: 67]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ó sọ pé: "Ẹ̀yin ìjọ mi, kò sí agọ̀ kan lára mi, ṣùgbọ́n dájúdájú èmi ni Òjíṣẹ́ kan láti ọ̀dọ̀ Olúwa gbogbo ẹ̀dá |