Quran with Yoruba translation - Surah Al-A‘raf ayat 68 - الأعرَاف - Page - Juz 8
﴿أُبَلِّغُكُمۡ رِسَٰلَٰتِ رَبِّي وَأَنَا۠ لَكُمۡ نَاصِحٌ أَمِينٌ ﴾
[الأعرَاف: 68]
﴿أبلغكم رسالات ربي وأنا لكم ناصح أمين﴾ [الأعرَاف: 68]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Mò ń jẹ́ àwọn iṣẹ́ Olúwa mi fun yín. Èmi sì ni onímọ̀ràn rere, olùfọkàntán fun yín |