Quran with Yoruba translation - Surah Al-Jinn ayat 4 - الجِن - Page - Juz 29
﴿وَأَنَّهُۥ كَانَ يَقُولُ سَفِيهُنَا عَلَى ٱللَّهِ شَطَطٗا ﴾
[الجِن: 4]
﴿وأنه كان يقول سفيهنا على الله شططا﴾ [الجِن: 4]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Dájúdájú òmùgọ̀ nínú wa máa ń sọ ìsọkúsọ nípa Allāhu |