Quran with Yoruba translation - Surah Al-Muddaththir ayat 18 - المُدثر - Page - Juz 29
﴿إِنَّهُۥ فَكَّرَ وَقَدَّرَ ﴾
[المُدثر: 18]
﴿إنه فكر وقدر﴾ [المُدثر: 18]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Dájúdájú ó ronú (lódì nípa al-Ƙur’ān). Ó sì pinnu (ọ̀rọ̀ kan nínú ẹ̀mí rẹ̀) |