Quran with Yoruba translation - Surah Al-Mursalat ayat 50 - المُرسَلات - Page - Juz 29
﴿فَبِأَيِّ حَدِيثِۭ بَعۡدَهُۥ يُؤۡمِنُونَ ﴾
[المُرسَلات: 50]
﴿فبأي حديث بعده يؤمنون﴾ [المُرسَلات: 50]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Nígbà náà, ọ̀rọ̀ wo ni wọn yóò gbàgbọ́ lẹ́yìn rẹ̀ |