Quran with Yoruba translation - Surah An-Naba’ ayat 14 - النَّبَإ - Page - Juz 30
﴿وَأَنزَلۡنَا مِنَ ٱلۡمُعۡصِرَٰتِ مَآءٗ ثَجَّاجٗا ﴾
[النَّبَإ: 14]
﴿وأنـزلنا من المعصرات ماء ثجاجا﴾ [النَّبَإ: 14]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Àti pé A sọ omi t’ó ń bọ́ tẹ̀léra wọn kalẹ̀ láti inú àwọn ẹ̀ṣújò |