Quran with Yoruba translation - Surah An-Naba’ ayat 20 - النَّبَإ - Page - Juz 30
﴿وَسُيِّرَتِ ٱلۡجِبَالُ فَكَانَتۡ سَرَابًا ﴾
[النَّبَإ: 20]
﴿وسيرت الجبال فكانت سرابا﴾ [النَّبَإ: 20]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Wọ́n máa mú àwọn àpáta rìn (bọ́ sí àyè mìíràn). Ó sì máa di ahúnpeéná |