Quran with Yoruba translation - Surah At-Takwir ayat 14 - التَّكوير - Page - Juz 30
﴿عَلِمَتۡ نَفۡسٞ مَّآ أَحۡضَرَتۡ ﴾
[التَّكوير: 14]
﴿علمت نفس ما أحضرت﴾ [التَّكوير: 14]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni (nígbà náà ni) ẹ̀mí (kọ̀ọ̀kan) yóò mọ ohun tí ó mú wá (nínú iṣẹ́ ire àti iṣẹ́ ibi) |