Quran with Yoruba translation - Surah Al-MuTaffifin ayat 7 - المُطَففين - Page - Juz 30
﴿كـَلَّآ إِنَّ كِتَٰبَ ٱلۡفُجَّارِ لَفِي سِجِّينٖ ﴾
[المُطَففين: 7]
﴿كلا إن كتاب الفجار لفي سجين﴾ [المُطَففين: 7]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Bẹ́ẹ̀ ni, dájúdájú ìwé iṣẹ́ àwọn ẹni ibi kúkú wà nínú Sijjīn |