Quran with Yoruba translation - Surah Al-Inshiqaq ayat 10 - الانشِقَاق - Page - Juz 30
﴿وَأَمَّا مَنۡ أُوتِيَ كِتَٰبَهُۥ وَرَآءَ ظَهۡرِهِۦ ﴾
[الانشِقَاق: 10]
﴿وأما من أوتي كتابه وراء ظهره﴾ [الانشِقَاق: 10]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ní ti ẹni tí wọ́n bá sì fún ní ìwé iṣẹ́ rẹ̀ láti ẹ̀yìn rẹ̀ |