Quran with Yoruba translation - Surah Al-Ghashiyah ayat 17 - الغَاشِية - Page - Juz 30
﴿أَفَلَا يَنظُرُونَ إِلَى ٱلۡإِبِلِ كَيۡفَ خُلِقَتۡ ﴾
[الغَاشِية: 17]
﴿أفلا ينظرون إلى الإبل كيف خلقت﴾ [الغَاشِية: 17]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Nítorí náà, ṣé wọn kò wo ràkúnmí, bí A ti ṣẹ̀dá rẹ̀ ni |