Quran with Yoruba translation - Surah Ad-duha ayat 7 - الضُّحى - Page - Juz 30
﴿وَوَجَدَكَ ضَآلّٗا فَهَدَىٰ ﴾
[الضُّحى: 7]
﴿ووجدك ضالا فهدى﴾ [الضُّحى: 7]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ó sì rí ọ ní aláìmọ̀nà (ìyẹn ṣíwájú ìsọ̀kalẹ̀ ìmísí). Ó sì fi ọ̀nà mọ̀ ọ́ |