Quran with Yoruba translation - Surah Yunus ayat 48 - يُونس - Page - Juz 11
﴿وَيَقُولُونَ مَتَىٰ هَٰذَا ٱلۡوَعۡدُ إِن كُنتُمۡ صَٰدِقِينَ ﴾
[يُونس: 48]
﴿ويقولون متى هذا الوعد إن كنتم صادقين﴾ [يُونس: 48]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Wọ́n ń wí pé: “Ìgbà wo ni àdéhùn yìí yóò ṣẹ tí ẹ bá jẹ́ olódodo?” |