Quran with Yoruba translation - Surah Yunus ayat 56 - يُونس - Page - Juz 11
﴿هُوَ يُحۡيِۦ وَيُمِيتُ وَإِلَيۡهِ تُرۡجَعُونَ ﴾
[يُونس: 56]
﴿هو يحيي ويميت وإليه ترجعون﴾ [يُونس: 56]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ó ń sọ ẹ̀dá di alààyè. Ó sì ń sọ ẹ̀dá di òkú. Ọ̀dọ̀ Rẹ̀ sì ni wọn yóò da yín padà sí |