Quran with Yoruba translation - Surah Hud ayat 22 - هُود - Page - Juz 12
﴿لَا جَرَمَ أَنَّهُمۡ فِي ٱلۡأٓخِرَةِ هُمُ ٱلۡأَخۡسَرُونَ ﴾
[هُود: 22]
﴿لا جرم أنهم في الآخرة هم الأخسرون﴾ [هُود: 22]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ní ti òdodo, dájúdájú àwọn gan-an ni ẹni òfò jùlọ ní Ọjọ́ Ìkẹ́yìn |