Quran with Yoruba translation - Surah Hud ayat 21 - هُود - Page - Juz 12
﴿أُوْلَٰٓئِكَ ٱلَّذِينَ خَسِرُوٓاْ أَنفُسَهُمۡ وَضَلَّ عَنۡهُم مَّا كَانُواْ يَفۡتَرُونَ ﴾
[هُود: 21]
﴿أولئك الذين خسروا أنفسهم وضل عنهم ما كانوا يفترون﴾ [هُود: 21]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Àwọn wọ̀nyẹn ni àwọn t’ó ṣe ẹ̀mí ara wọn lófò. Ohun tí wọ́n sì ń dá ní àdápa irọ́ ti di òfò mọ́ wọn lọ́wọ́ |