Quran with Yoruba translation - Surah Hud ayat 98 - هُود - Page - Juz 12
﴿يَقۡدُمُ قَوۡمَهُۥ يَوۡمَ ٱلۡقِيَٰمَةِ فَأَوۡرَدَهُمُ ٱلنَّارَۖ وَبِئۡسَ ٱلۡوِرۡدُ ٱلۡمَوۡرُودُ ﴾
[هُود: 98]
﴿يقدم قومه يوم القيامة فأوردهم النار وبئس الورد المورود﴾ [هُود: 98]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ó máa ṣíwájú ìjọ rẹ̀ ní Ọjọ́ Àjíǹde. Ó sì máa kó wọn wọ inú Iná. Wíwọ Iná náà sì burú |