Quran with Yoruba translation - Surah An-Nahl ayat 17 - النَّحل - Page - Juz 14
﴿أَفَمَن يَخۡلُقُ كَمَن لَّا يَخۡلُقُۚ أَفَلَا تَذَكَّرُونَ ﴾
[النَّحل: 17]
﴿أفمن يخلق كمن لا يخلق أفلا تذكرون﴾ [النَّحل: 17]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ǹjẹ́ Ẹni tí Ó dá ẹ̀dá dà bí ẹni tí kò dá ẹ̀dá bí? Nítorí náà, ṣé ẹ ò níí lo ìrántí ni |