Quran with Yoruba translation - Surah An-Nahl ayat 19 - النَّحل - Page - Juz 14
﴿وَٱللَّهُ يَعۡلَمُ مَا تُسِرُّونَ وَمَا تُعۡلِنُونَ ﴾
[النَّحل: 19]
﴿والله يعلم ما تسرون وما تعلنون﴾ [النَّحل: 19]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Àti pé Allāhu mọ ohun tí ẹ̀ ń fi pamọ́ àti ohun tí ẹ̀ ń ṣe àfihàn rẹ̀ |