Quran with Yoruba translation - Surah An-Nahl ayat 20 - النَّحل - Page - Juz 14
﴿وَٱلَّذِينَ يَدۡعُونَ مِن دُونِ ٱللَّهِ لَا يَخۡلُقُونَ شَيۡـٔٗا وَهُمۡ يُخۡلَقُونَ ﴾
[النَّحل: 20]
﴿والذين يدعون من دون الله لا يخلقون شيئا وهم يخلقون﴾ [النَّحل: 20]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Àwọn (òrìṣà) tí wọ́n ń pè lẹ́yìn Allāhu; wọn kò lè dá kiní kan. Allāhu l’Ó sì ṣẹ̀dá wọn |