Quran with Yoruba translation - Surah An-Nahl ayat 34 - النَّحل - Page - Juz 14
﴿فَأَصَابَهُمۡ سَيِّـَٔاتُ مَا عَمِلُواْ وَحَاقَ بِهِم مَّا كَانُواْ بِهِۦ يَسۡتَهۡزِءُونَ ﴾
[النَّحل: 34]
﴿فأصابهم سيئات ما عملوا وحاق بهم ما كانوا به يستهزئون﴾ [النَّحل: 34]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Nítorí náà, àwọn aburú ohun tí wọ́n ṣe níṣẹ́ ṣẹlẹ̀ sí wọn. Àti pé ohun tí wọ́n ń fi ṣe yẹ̀yẹ́ sì dìyà t’ó yí wọn po |