Quran with Yoruba translation - Surah An-Nahl ayat 50 - النَّحل - Page - Juz 14
﴿يَخَافُونَ رَبَّهُم مِّن فَوۡقِهِمۡ وَيَفۡعَلُونَ مَا يُؤۡمَرُونَ۩ ﴾
[النَّحل: 50]
﴿يخافون ربهم من فوقهم ويفعلون ما يؤمرون﴾ [النَّحل: 50]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Wọ́n ń páyà Olúwa wọn t’Ó ń bẹ lókè wọn. Wọ́n sì ń ṣe ohun tí À ń pa láṣẹ fún wọn |