Quran with Yoruba translation - Surah Al-Isra’ ayat 10 - الإسرَاء - Page - Juz 15
﴿وَأَنَّ ٱلَّذِينَ لَا يُؤۡمِنُونَ بِٱلۡأٓخِرَةِ أَعۡتَدۡنَا لَهُمۡ عَذَابًا أَلِيمٗا ﴾
[الإسرَاء: 10]
﴿وأن الذين لا يؤمنون بالآخرة أعتدنا لهم عذابا أليما﴾ [الإسرَاء: 10]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Dájúdájú àwọn tí kò gba Ọjọ́ Ìkẹ́yìn gbọ́, A ti pèsè ìyà ẹlẹ́ta-eléro sílẹ̀ dè wọ́n |