Quran with Yoruba translation - Surah Al-Isra’ ayat 11 - الإسرَاء - Page - Juz 15
﴿وَيَدۡعُ ٱلۡإِنسَٰنُ بِٱلشَّرِّ دُعَآءَهُۥ بِٱلۡخَيۡرِۖ وَكَانَ ٱلۡإِنسَٰنُ عَجُولٗا ﴾
[الإسرَاء: 11]
﴿ويدع الإنسان بالشر دعاءه بالخير وكان الإنسان عجولا﴾ [الإسرَاء: 11]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ènìyàn ń tọrọ aburú bí ó ṣe ń tọrọ ohun rere; ènìyàn sì jẹ́ olùkánjú |