×

So pe: “E gba al-Ƙur’an gbo tabi e o gba a gbo, 17:107 Yoruba translation

Quran infoYorubaSurah Al-Isra’ ⮕ (17:107) ayat 107 in Yoruba

17:107 Surah Al-Isra’ ayat 107 in Yoruba (اليوربا)

Quran with Yoruba translation - Surah Al-Isra’ ayat 107 - الإسرَاء - Page - Juz 15

﴿قُلۡ ءَامِنُواْ بِهِۦٓ أَوۡ لَا تُؤۡمِنُوٓاْۚ إِنَّ ٱلَّذِينَ أُوتُواْ ٱلۡعِلۡمَ مِن قَبۡلِهِۦٓ إِذَا يُتۡلَىٰ عَلَيۡهِمۡ يَخِرُّونَۤ لِلۡأَذۡقَانِۤ سُجَّدٗاۤ ﴾
[الإسرَاء: 107]

So pe: “E gba al-Ƙur’an gbo tabi e o gba a gbo, dajudaju awon ti A fun ni imo siwaju (isokale) re, nigba ti won ba n ke e fun won, won yoo doju bole, ti won n fori kanle (fun Allahu)

❮ Previous Next ❯

ترجمة: قل آمنوا به أو لا تؤمنوا إن الذين أوتوا العلم من قبله, باللغة اليوربا

﴿قل آمنوا به أو لا تؤمنوا إن الذين أوتوا العلم من قبله﴾ [الإسرَاء: 107]

Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Sọ pé: “Ẹ gba al-Ƙur’ān gbọ́ tàbí ẹ ò gbà á gbọ́, dájúdájú àwọn tí A fún ní ìmọ̀ ṣíwájú (ìsọ̀kalẹ̀) rẹ̀, nígbà tí wọ́n bá ń ké e fún wọn, wọn yóò dojú bolẹ̀, tí wọ́n ń forí kanlẹ̀ (fún Allāhu)
❮ Previous Next ❯

Verse in more languages

Transliteration Bangla Bosnian German English Persian French Hindi Indonesian Kazakh Dutch Russian Spanish Turkish Urdu Uzbek