×

(Ranti) ojo ti (Allahu) yoo so pe: “E pe awon akegbe Mi 18:52 Yoruba translation

Quran infoYorubaSurah Al-Kahf ⮕ (18:52) ayat 52 in Yoruba

18:52 Surah Al-Kahf ayat 52 in Yoruba (اليوربا)

Quran with Yoruba translation - Surah Al-Kahf ayat 52 - الكَهف - Page - Juz 15

﴿وَيَوۡمَ يَقُولُ نَادُواْ شُرَكَآءِيَ ٱلَّذِينَ زَعَمۡتُمۡ فَدَعَوۡهُمۡ فَلَمۡ يَسۡتَجِيبُواْ لَهُمۡ وَجَعَلۡنَا بَيۡنَهُم مَّوۡبِقٗا ﴾
[الكَهف: 52]

(Ranti) ojo ti (Allahu) yoo so pe: “E pe awon akegbe Mi ti e so nipa won lai ni eri lowo (pe olusipe ni won).” Won pe won. Won ko si da won lohun. A si ti fi koto iparun saaarin won

❮ Previous Next ❯

ترجمة: ويوم يقول نادوا شركائي الذين زعمتم فدعوهم فلم يستجيبوا لهم وجعلنا بينهم, باللغة اليوربا

﴿ويوم يقول نادوا شركائي الذين زعمتم فدعوهم فلم يستجيبوا لهم وجعلنا بينهم﴾ [الكَهف: 52]

Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
(Rántí) ọjọ́ tí (Allāhu) yóò sọ pé: “Ẹ pe àwọn akẹgbẹ́ Mi tí ẹ sọ nípa wọn láì ní ẹ̀rí lọ́wọ́ (pé olùṣìpẹ̀ ni wọ́n).” Wọ́n pè wọ́n. Wọn kò sì dá wọn lóhùn. A sì ti fi kòtò ìparun sáààrin wọn
❮ Previous Next ❯

Verse in more languages

Transliteration Bangla Bosnian German English Persian French Hindi Indonesian Kazakh Dutch Russian Spanish Turkish Urdu Uzbek