×

(Ranti) nigba ti (Anabi) Musa so fun omo-odo re pe: "Ng o 18:60 Yoruba translation

Quran infoYorubaSurah Al-Kahf ⮕ (18:60) ayat 60 in Yoruba

18:60 Surah Al-Kahf ayat 60 in Yoruba (اليوربا)

Quran with Yoruba translation - Surah Al-Kahf ayat 60 - الكَهف - Page - Juz 15

﴿وَإِذۡ قَالَ مُوسَىٰ لِفَتَىٰهُ لَآ أَبۡرَحُ حَتَّىٰٓ أَبۡلُغَ مَجۡمَعَ ٱلۡبَحۡرَيۡنِ أَوۡ أَمۡضِيَ حُقُبٗا ﴾
[الكَهف: 60]

(Ranti) nigba ti (Anabi) Musa so fun omo-odo re pe: "Ng o nii ye rin titi mo maa fi de ibi ti odo meji ti pade tabi (titi) mo maa fi lo opolopo odun

❮ Previous Next ❯

ترجمة: وإذ قال موسى لفتاه لا أبرح حتى أبلغ مجمع البحرين أو أمضي, باللغة اليوربا

﴿وإذ قال موسى لفتاه لا أبرح حتى أبلغ مجمع البحرين أو أمضي﴾ [الكَهف: 60]

Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
(Rántí) nígbà tí (Ànábì) Mūsā sọ fún ọmọ-ọ̀dọ̀ rẹ̀ pé: "N̄g ò níí yé rìn títí mo máa fi dé ibi tí odò méjì ti pàdé tàbí (títí) mo máa fi lo ọ̀pọ̀lọ́pọ̀ ọdún
❮ Previous Next ❯

Verse in more languages

Transliteration Bangla Bosnian German English Persian French Hindi Indonesian Kazakh Dutch Russian Spanish Turkish Urdu Uzbek