Quran with Yoruba translation - Surah Al-Kahf ayat 72 - الكَهف - Page - Juz 15
﴿قَالَ أَلَمۡ أَقُلۡ إِنَّكَ لَن تَسۡتَطِيعَ مَعِيَ صَبۡرٗا ﴾
[الكَهف: 72]
﴿قال ألم أقل إنك لن تستطيع معي صبرا﴾ [الكَهف: 72]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni (Kidr) sọ pé: “Ǹjẹ́ mi ò sọ fún ọ pé dájúdájú o ò níí lè ṣe sùúrú pẹ̀lú mi.” |