Quran with Yoruba translation - Surah Al-Kahf ayat 73 - الكَهف - Page - Juz 15
﴿قَالَ لَا تُؤَاخِذۡنِي بِمَا نَسِيتُ وَلَا تُرۡهِقۡنِي مِنۡ أَمۡرِي عُسۡرٗا ﴾
[الكَهف: 73]
﴿قال لا تؤاخذني بما نسيت ولا ترهقني من أمري عسرا﴾ [الكَهف: 73]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni (Ànábì Mūsā) sọ pé: “Má ṣe bá mi wí nípa ohun tí mo gbàgbé. Má sì ṣe kó ìnira bá mi nínú ọ̀rọ̀ (ìrìn-àjò) mi (pẹ̀lú rẹ).” |