Quran with Yoruba translation - Surah Maryam ayat 33 - مَريَم - Page - Juz 16
﴿وَٱلسَّلَٰمُ عَلَيَّ يَوۡمَ وُلِدتُّ وَيَوۡمَ أَمُوتُ وَيَوۡمَ أُبۡعَثُ حَيّٗا ﴾
[مَريَم: 33]
﴿والسلام علي يوم ولدت ويوم أموت ويوم أبعث حيا﴾ [مَريَم: 33]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Àlàáfíà ni fún mi ní ọjọ́ tí wọ́n bí mi, àti ní ọjọ́ tí mo máa kú àti ní ọjọ́ tí Wọ́n á gbé mi dìde ní alààyè (ní Ọjọ́ Àjíǹde) |