Quran with Yoruba translation - Surah Maryam ayat 34 - مَريَم - Page - Juz 16
﴿ذَٰلِكَ عِيسَى ٱبۡنُ مَرۡيَمَۖ قَوۡلَ ٱلۡحَقِّ ٱلَّذِي فِيهِ يَمۡتَرُونَ ﴾
[مَريَم: 34]
﴿ذلك عيسى ابن مريم قول الحق الذي فيه يمترون﴾ [مَريَم: 34]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ìyẹn ni (Ànábì) ‘Īsā ọmọ Mọryam. (Èyí jẹ́) ọ̀rọ̀ òdodo tí àwọn (yẹhudi àti nasara) ń ṣeyèméjì nípa rẹ̀ |