Quran with Yoruba translation - Surah Maryam ayat 74 - مَريَم - Page - Juz 16
﴿وَكَمۡ أَهۡلَكۡنَا قَبۡلَهُم مِّن قَرۡنٍ هُمۡ أَحۡسَنُ أَثَٰثٗا وَرِءۡيٗا ﴾
[مَريَم: 74]
﴿وكم أهلكنا قبلهم من قرن هم أحسن أثاثا ورئيا﴾ [مَريَم: 74]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Àti pé mélòó mélòó nínú àwọn ìran tí A ti parẹ́ ṣíwájú wọn, tí wọ́n dára jùlọ ní ọrọ̀ (ayé) àti ní ìrísí |