Quran with Yoruba translation - Surah Al-Baqarah ayat 152 - البَقَرَة - Page - Juz 2
﴿فَٱذۡكُرُونِيٓ أَذۡكُرۡكُمۡ وَٱشۡكُرُواْ لِي وَلَا تَكۡفُرُونِ ﴾
[البَقَرَة: 152]
﴿فاذكروني أذكركم واشكروا لي ولا تكفرون﴾ [البَقَرَة: 152]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Nítorí náà, ẹ rántí Mi, Mo máa rántí yín. Ẹ dúpẹ́ fún Mi, ẹ má ṣàì moore sí Mi |