Quran with Yoruba translation - Surah Al-Baqarah ayat 46 - البَقَرَة - Page - Juz 1
﴿ٱلَّذِينَ يَظُنُّونَ أَنَّهُم مُّلَٰقُواْ رَبِّهِمۡ وَأَنَّهُمۡ إِلَيۡهِ رَٰجِعُونَ ﴾
[البَقَرَة: 46]
﴿الذين يظنون أنهم ملاقو ربهم وأنهم إليه راجعون﴾ [البَقَرَة: 46]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni àwọn t’ó mọ̀ pé dájúdájú àwọn yóò pàdé Olúwa wọn, àti pé dájúdájú àwọn yóò padà sí ọ̀dọ̀ Rẹ̀ |